CCC Hymn 432

Jehoẹah alayọ

YorubaHarvest
Hymn 432Yoruba
Jehoẹah alayọ Titilawa ibati jẹ Nigbati iji ati isan Aye fẹ lati gbewa lọ Irẹ lotọ lati dawọ rẹ duro Awa siwaju Rẹ lati bẹbẹ fun Agbara isẹgun Agbara igbega Pẹlu awọn ibukun mimọ Rẹ Titi lọ dopin. Amin