Hymn 361·YorubaCopy Hymn 3611: Ayọ nla kun ọkan mi Ayọ nla kun ọkan mi Ayọ, ayọ, ayọ Ayọ nla kun ọkan mi 2: Iyin nla kun ọkan mi Iyin nla kun ọkan mi Iyin, iyin, iyin Iyin nla kun ọkan mi 3: Ogo ni fun Baba Ogo ni fun Ọmọ Ogo, ogo, ogo Ni fun mẹta lọkan. Amin