CCC Hymn 361

1: Ayọ nla kun ọkan mi

YorubaGlory
Hymn 361Yoruba
1: Ayọ nla kun ọkan mi Ayọ nla kun ọkan mi Ayọ, ayọ, ayọ Ayọ nla kun ọkan mi 2: Iyin nla kun ọkan mi Iyin nla kun ọkan mi Iyin, iyin, iyin Iyin nla kun ọkan mi 3: Ogo ni fun Baba Ogo ni fun Ọmọ Ogo, ogo, ogo Ni fun mẹta lọkan. Amin