CCC Hymn 314

1: Ẹjẹ ka kọrin yin wa soke

YorubaPraises
Hymn 314Yoruba
1: Ẹjẹ ka kọrin yin wa soke Iyin Ọlọrun ni yio jẹ Ẹjẹ ka kọrin yin wa soke Iyin Ọlọrun ni yio jẹ 2: Ẹ wo bibọ Jesu Oluwa wa Pẹlu awọn ogun ọrun Wọn fiyin ogo, ọpẹ fun Baba 3: Ijọba mimọ ti Jesu pese Awọn ayanfẹ ni o ni Nbiti duru-wura nke tantan Yii agbala ni ka 4: Emi Ọlọrun n’imọlẹ ibẹ Ogo aiyeraiye leyi Fun waw ọmọ ijọ mimọ t’aiye Bi a ba se ifẹ rẹ 5: Nirorina ẹjẹ ka sin Baba Pẹlu itẹriba oun ifẹ Ka fifeẹ kufẹ aiye silẹ Ti yio mu wa kọ’sẹ 6: Halleluyah, halleluyah Hossana lorin wa ojẹ Ni’gbati Baba ba de Lati wakowa lọ 7: Ẹjẹ ka kọrin yin wa soke Iyin Ọlọrun ni yio jẹ Ẹjẹ ka kọrin yin wa soke Iyin Ọlọrun ni yio jẹ. Amin