Hymn 299·YorubaCopy Hymn 2991: Mo f’aiye mi fun Jesu Mo f’aiye mi fun Jesu Mo f’aiye mi fun Jesu K’aiye mi ba le dara 2: Baba alawo ko le gba ni la Onisangun ko le gba ni la Adahunse Ko le gba ni la A fi Jesu nikan. Amin