Hymn 297Yoruba
Ch: Emi ni Emi ni Emi ni Ijo Mimọ
1: Emi ni Emi ni Emi ni Ijo Mimọ
Orun osu pa ni ami na
Oti nu imọlẹ tan s’aiye
Gbogbo ẹda aiye si n’wariri
Ch: Emi ni, Emi ni, Emi ni Ijo Mimọ
2: Ẹyin ayanfẹ ni nu ‘jọ mimọ
Eṣe tija fẹfẹ yin kun f’ẹsẹ
Ironu piwada ni rubọ na
Ch: Emi ni, Emi ni, Emi ni Ijo Mimọ
3: Ẹyin ayanfẹ ninu ‘jọ mimọ
Ẹṣe tẹ ro ọkan yin kun fun mi,
Ironu piwada ni rubọ na
Ch: Emi ni, Emi ni, Emi ni Ijo Mimọ
4: Ẹyin ayanfe ninu ‘jo mimọ
Eṣe ti ọrọ ẹnu yin kun fun ẹtan
Ironu piwada ni rubọ na
Ch: Emi ni, Emi ni, Emi ni Ijo Mimọ
5: Ẹyin ayanfe ninu ‘jo mimọ
Eṣe ti isẹ ọwọ yin kun fun ika
Ironu piwada ni rubọ na
Ch: Emi ni, Emi ni, Emi ni Ijo Mimọ
6: Emi Kristi bọ adeogo ọrun silẹ
Oku fun yin kẹ ba le ye
Egba mi gbọ emi l’Oluwa yin
Ch: Emi ni, Emi ni, Emi ni Ijo Mimọ
Ẹyin ayanfe ninu ‘jo mimọ
Mo de pelu ade mimọ t’ọrun
Ẹnura lati gba ade ogo na
Ch: Emi ni, Emi ni, Emi ni Ijo Mimọ.
Amin
