CCC Hymn 297

Ch: Emi ni Emi ni Emi ni Ijo Mimọ

YorubaGood News
Hymn 297Yoruba
Ch: Emi ni Emi ni Emi ni Ijo Mimọ 1: Emi ni Emi ni Emi ni Ijo Mimọ Orun osu pa ni ami na Oti nu imọlẹ tan s’aiye Gbogbo ẹda aiye si n’wariri Ch: Emi ni, Emi ni, Emi ni Ijo Mimọ 2: Ẹyin ayanfẹ ni nu ‘jọ mimọ Eṣe tija fẹfẹ yin kun f’ẹsẹ Ironu piwada ni rubọ na Ch: Emi ni, Emi ni, Emi ni Ijo Mimọ 3: Ẹyin ayanfẹ ninu ‘jọ mimọ Ẹṣe tẹ ro ọkan yin kun fun mi, Ironu piwada ni rubọ na Ch: Emi ni, Emi ni, Emi ni Ijo Mimọ 4: Ẹyin ayanfe ninu ‘jo mimọ Eṣe ti ọrọ ẹnu yin kun fun ẹtan Ironu piwada ni rubọ na Ch: Emi ni, Emi ni, Emi ni Ijo Mimọ 5: Ẹyin ayanfe ninu ‘jo mimọ Eṣe ti isẹ ọwọ yin kun fun ika Ironu piwada ni rubọ na Ch: Emi ni, Emi ni, Emi ni Ijo Mimọ 6: Emi Kristi bọ adeogo ọrun silẹ Oku fun yin kẹ ba le ye Egba mi gbọ emi l’Oluwa yin Ch: Emi ni, Emi ni, Emi ni Ijo Mimọ Ẹyin ayanfe ninu ‘jo mimọ Mo de pelu ade mimọ t’ọrun Ẹnura lati gba ade ogo na Ch: Emi ni, Emi ni, Emi ni Ijo Mimọ. Amin