Hymn 268Yoruba
1: Awẹ ọ ninu ẹjẹ
Ọdọaguntan
Imọle yi lo sọkalẹ yi
Maleka ti ‘jọ mimọ
Sọkalẹ pẹlu agbara nla Rẹ
Lati bi gbobgo ogun esu wo
Wa gbe inu ile mimọ yi,
2: Talo dabi Ọlọrun mimọ
Wa fi agbara mimọ nah an fun wa
Maleka ti ‘jọ mimọ
Sọkalẹ pẹlu agbara nla Rẹ
Lati bi gbobgo ogun esu wo
Wa gbe ile mimọ yi
3: Awa nyọ larin ogun ọrun mimọ
Kosi ohun ẹru kankan mọ
Maleka ti ‘jọ mimọ
Sọkalẹ pẹlu agbara nla Rẹ
Lati bi gbobgo ogun esu wo
Wa gbe ile mimọ yi
4: Iwọ Oluṣọ aguntan nla
Wa pa agbo agutan rẹ mọ
Maleka ti ‘jọ mimọ
Sọkalẹ pẹlu agbara nla Rẹ
Lati bi gbobgo ogun esu wo
Wa gbe ile mimọ yi
5: Ẹmi ọrun wa fara han funwa
Wa bi adaba mimọ si wa
Maleka ti ‘jọ mimọ
Sọkalẹ pẹlu agbara nla Rẹ
Lati bi gbobgo ogun esu wo
Wa gbe ile mimọ yi.
Amin
