CCC Hymn 268

1: Awẹ ọ ninu ẹjẹ

YorubaSpiritual Power
Hymn 268Yoruba
1: Awẹ ọ ninu ẹjẹ Ọdọaguntan Imọle yi lo sọkalẹ yi Maleka ti ‘jọ mimọ Sọkalẹ pẹlu agbara nla Rẹ Lati bi gbobgo ogun esu wo Wa gbe inu ile mimọ yi, 2: Talo dabi Ọlọrun mimọ Wa fi agbara mimọ nah an fun wa Maleka ti ‘jọ mimọ Sọkalẹ pẹlu agbara nla Rẹ Lati bi gbobgo ogun esu wo Wa gbe ile mimọ yi 3: Awa nyọ larin ogun ọrun mimọ Kosi ohun ẹru kankan mọ Maleka ti ‘jọ mimọ Sọkalẹ pẹlu agbara nla Rẹ Lati bi gbobgo ogun esu wo Wa gbe ile mimọ yi 4: Iwọ Oluṣọ aguntan nla Wa pa agbo agutan rẹ mọ Maleka ti ‘jọ mimọ Sọkalẹ pẹlu agbara nla Rẹ Lati bi gbobgo ogun esu wo Wa gbe ile mimọ yi 5: Ẹmi ọrun wa fara han funwa Wa bi adaba mimọ si wa Maleka ti ‘jọ mimọ Sọkalẹ pẹlu agbara nla Rẹ Lati bi gbobgo ogun esu wo Wa gbe ile mimọ yi. Amin