Hymn 134Yoruba
1: Ẹkọ orin didun ni
Pade ọmọ Ọlọrun
T’onbọ pẹlu ogo
Lati wa gbawa la
Pade ọmọ Ọlọrun
2: Ẹkọ orin didun ni
Ijọ mimọ sọkalẹ
La wẹ lẹsẹ mọ
Yo ma tọ Baba lọ
Ẹkọ orin didun ni
Ijọ mimọ sọkalẹ
3: Ẹyin ọmọ Kristi
Ẹjẹka jumọ sin
Yo gbọ adura wa
Yo ko lọ ọdọ Baba
Ẹyin ọmọ Kristi
Ẹjẹkajumọ sin.
Amin
