CCC Hymn 134

1: Ẹkọ orin didun ni

YorubaPalm Sunday
Hymn 134Yoruba
1: Ẹkọ orin didun ni Pade ọmọ Ọlọrun T’onbọ pẹlu ogo Lati wa gbawa la Pade ọmọ Ọlọrun 2: Ẹkọ orin didun ni Ijọ mimọ sọkalẹ La wẹ lẹsẹ mọ Yo ma tọ Baba lọ Ẹkọ orin didun ni Ijọ mimọ sọkalẹ 3: Ẹyin ọmọ Kristi Ẹjẹka jumọ sin Yo gbọ adura wa Yo ko lọ ọdọ Baba Ẹyin ọmọ Kristi Ẹjẹkajumọ sin. Amin